Skip to Main Content

Science Resources | ÌMỌ̀-ÌJÌNLẸ̀ SÁYẸ́NSÌ

Ṣe àférí eto-ẹkọ, àwọn eto Ìjọba fún ẹkọ kíkọ yìí, àti àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ mìíràn tí ó jọmọ́ọ láti ṣe àtìlẹyìn ìrìn-àjò ìkẹ́kọ̀ọ́ ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ọmọọ̀ rẹ. Ètò ìwé-ẹ̀kọ́ tí Ìjọba f’ọwọ́ sí ní Ontario, ní ìlú Kánádà, la ó máa ṣàmúlò lóríi ojú-ìwé yìí.

Science Curriculum Resources | Àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ ìwé-ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì

Ṣàwarí àwọn ìwé-ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ti Ontario fún àwọn kíláàsì 6-8 àti kíláàsì 9 (de-streamed). Ṣe àkíyèsí àwọn agbègbè ẹ̀kọ́ pàtàkì tí ó ṣe àtìlẹyìn ìdàgbàsókè ìwé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ọmọọ̀ rẹ.

Explore concise summaries of expectations and key concepts for Science curriculum. Understand in more detail what your child will learn in each grade.

Ministry Resources | Àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ láti ọ̀dọọ̀ Ìjọba

This guide illuminates the transition to a single science course, outlining key changes, the curriculum content, and how you can support your child’s learning.

Discover insights into Ontario’s updated science and technology curriculum for Grades 1 to 8. Explore changes introduced in the winter of 2022.