Resources for Families | Ẹ káàbọ̀ sí ojú-ìwé Ìdílé ti ESCAPE Projects!
Èyí jẹ́ ààyè tí a yà sọ́tọ fún-un yín, láti lè ṣe onírúurú ìrànlọ́wọ́ fún-un yín lóríi ìdàgbàsókè, ìwárìrì àti àṣeyọrí ọmọ yín nínú ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́ńsì àti Ìṣirò. Ẹ ṣàwárí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun àmúlò ètò-ẹ̀kọ́ tí ó lè ṣe ìrànlọ́wọ́ fún-un yín láti se ìtọ́sọ́nà àti àtìlẹyìn rere nínúu ìrìn-àjò ètò-ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ yín. Ètò ìwé-ẹ̀kọ́ tí Ìjọba f’ọwọ́ sí ní Ontario, ní ìlú Kánádà, la ó máa ṣàmúlò lóríi ojú-ìwé yìí.
Science Resources | ÌMỌ̀-ÌJÌNLẸ̀ SÁYẸ́NSÌ
View our science resources for families.
Related Resources | Àwọn ohun àmúlò ẹ̀kọ́ tó jọmọ́ ti òkè yìí
View other related resources for families.