Skip to Main Content

Math Resources | ÌṢIRÒ

Ṣe àférí eto-ẹkọ, àwọn eto Ìjọba fún ẹkọ kíkọ yìí, àti àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ mìíràn tí ó jọmọ́ọ láti ṣe àtìlẹyìn ìrìn-àjò ìkẹ́kọ̀ọ́ ẹ̀kọ́ Ìṣirò ọmọọ̀ rẹ. Ètò ìwé-ẹ̀kọ́ tí Ìjọba f’ọwọ́ sí ní Ontario, ní ìlú Kánádà, la ó máa ṣàmúlò lóríi ojú-ìwé yìí.

Math Curriculum Resources | Àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ ìwé-ẹ̀kọ́ Ìṣirò

Math Ministry Resources | Àwọn ohun èlò ìkẹ́kọ̀ọ́ láti ọ̀dọọ̀ Ìjọba